Loading...

Download
  • Genre:World Music/Folklore
  • Year of Release:2001

Lyrics

Eyin alase ti nbe lori alefa

Alefa ijoba leleka-njeka

Eyin ti nsisee 're

Ti nsise idagbasoke

Tilu ati ti gbogbo eniyan

Mo kiiyin e o saseye e o ni mosi kehin laye

Eyin tojepe ibi kobaje leyin nduro si

Ipade kobaje leyin nse kiri

Toje tara yin nikan leyin nja fun

Ojo esin yin tisu dede, ojo eleya yin kola


Sugbon ejeka fipile lele o, ipile to dara

Ipile to dara

Ka fipile lele o, ipile to dara

Atijoba atara ilu gbogbo, ipile to dara

Ati gbogbo oselu pata, ipile to dara

Ipile rere se pataki, ipile to dara

Iyen ni Solid Foundation, ipile to dara

Ipile to dara

Iru eeyan wo loludije je, ipile to dara

Ki loludije ntori e dije, ipile to dara

Ki loludibo ntori e dibo, ipile to dara

Ki lojuse oludije toba wole, ipile to dara

Ki loun tofeese lori alefa, ipile to dara

Ki lanfani oludibo lehin idibo, ipile to dara

Ki lanfani kowa wa, ipile to dara

Ninu ijoba tiwa-tiwa, ipile to dara

Iyen loye ko jewalogun, ipile to dara

Pelu adehun atibura to muna doko, ipile to dara

Kale rohun fi maa sinrawa nigbere ipako, ipile to dara

Yatosi ka maa je nile oro je nile eegun, ipile to dara

Lasiko ipolongo saaju idibo, ipile to dara

Kayeese folow-folow aini-gbongbo, ipile to dara

Solid Foundation, ipile to dara

Ipile to dara

Se o gbagbe Anti-corruption, ipile to dara

Kajo gbogun tiwa ibaje, ipile to dara

Asiko to ka fipile lele o, ipile to dara

E jeka fipile lele, ipile to dara


E jeka sowopo, kajo satunse

E jeka sowopo, kajo satunse

Eyi tobaje temi, malo satunse

Eyi tobaje tie, kolo satunse

Toba wu e koogbo, toba wu e koogbo

Toba wu e koogba, toba wu e koogba

Toba wu e kolo satunse, toba wu e kolo satunse

Toba wuyin kelo satunse, toba wuyin kelo satunse

Baba lo ranmi nise, baba lo ranmi nise

Eledumare lo ranmi nise, eledumare lo ranmi nise

Mosi ti jise to ranmi, mosi ti jise to ranmi

Moti jise to ranmi, moti jise to ranmi

Mo jise fun e o, orun mi mo o

Orun mi mo o

Mo jise fun e oo, orun mi mo o

Omo Nigeria mo jise fun yin o, orun mi mo o

Omo Africa mo jise fun yin o, orun mi mo o

Teeba fi gbigbo salaigbo, orun mi mo o

Ewu nbe lojo 'waju, orun mi mo o

Amo mo jise fun yin o, orun mi mo o

Eyin alase mo jise fun yin o, orun mi mo o

Gbogbo ara ilu mo jise fun yin oo, orun mi mo o

Moti jise fun yin o, orun mi mo o

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234
          -You can log in via below methods-
          Reset password via e-mail
          -or-
          Reset password via e-mail
          Feedback on resetting password
          * It may take a longer time

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status