![Ilu Ibadan](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/18/4ffe6dd1633148099631c0d98098624d_464_464.jpg)
Ilu Ibadan Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2015
Lyrics
Nile yoruba, lataye awon baba wa
Ani nile yoruba lataye awon baba wa
Ilu kookan lo leto tanfi nmeni tiyo joba
Laarin awon omo oba
Won lafwon afobaje
Won si ni biwon se njoba lailo sile ejo rara
Sugbon lode oni gbogbo e nati yipada
Nitori owo ati imotara eni nikan
Tiwon o baa dele ejo
Won kotii moba tuntun
Adajo niyoo seniti o joba
Alabajo tigba ile ko roju mo
Tawo ile koraye mo
Amosa, moki gbogbo ibadan
Ibadan mesiogo nile oluyole
Eyin ajorosun, omo ajegbin tan,
Fi ikarawun fori mun
Ibadan ni momo, mio ma mo layipo
Mo kawon baba nla yin
Tiwon seto oba jije , onisese-ntele
Ti kii lariwo lo, ti kii dale ejo
Mosi kan saara siyin,
Latiran-deran titi tofi dasiko yi
Laiye awon ilana eto adayeba, laifolaju baluje
Opo ilu niwon ti nso nipa ibadan
P'arugbo nafi njoba
Beenaa ni, arugbo ni arugb o ni
Ilu ntuba o otuse
Arugbo ni arugbo ni
Omode ilu nroju
Arugbo ni arugbo ni
Agba ilu nraye
Arugbo ni arugbo ni
Omo onile nsorire
Arugbo ni arugbo ni
Alejo nsorire
Arugbo ni arugbo ni
ilu ntobi si looo
Ko ma ma nibaje
Oba oluwa maje 'badan obaje o,
Lola Oluwa koma mani baje
Koma mani daru
Oba Oluwa maje 'badan o daru o
Lola Oluwa koma mani daru