![Eleko idere](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/05/18d4c32c49d4491a9abb71b300c43f3a_464_464.jpg)
Eleko idere Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:1984
Lyrics
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka aa
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Bi o bafile nla ji kolekole
Iyen o ma pe koma jale die si
Bi o baa si fodede re jiyawo agbere
Iyen o pe koma fara e fale lo
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun ayokele Igba
O loko ofurufu koda o tun ni toju omi
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Moni bi o baa file nla jin kolekole
Bi a baa file nla jin kolekole
Iyen o'kuku pe koma jale die si
Bi baa si fodede re jin yawo agbere
Iyen o'mama ni koma sesina kiri
Eleko o'dere seboo loo jere
O loko ofurufu o si tun ni toju omi
Ile bi ogun ayokele igba a
O fayinrin gbaja o si tun lekenka aa
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
Eleko o'dere seboo loo jere
O roso dudu o roso pupa
O laya dudu
O si tun laya pupa
Ile bi ogun car bi igba
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
O fayinrin gbaja o si tun lekenka
Eleko o'dere seboo loo jere
Ile bi ogun ayokele igba
Eleko o'dere seboo loo jere
O loko ofurufu o si tun ni toju omi
Eleko o'dere seboo loo jere