![Eyin Ni Ndakuko](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/18/4ffe6dd1633148099631c0d98098624d_464_464.jpg)
Eyin Ni Ndakuko Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2015
Lyrics
Eyin agbalagba teti goke odo
Eyin agbalagba teti goke odo
Eyin agbalagba teti goke odo
Eyin agbalagba teti goke odo
E ma goke odo tan kee bori afara je
E ma goke odo tan kee fake jafara
E ma g'akaso tan, kee pakaso da
E ma g'akaso tan, kee taari akaso lule
E ma se ise igi araba
To nda toto pagi wewe to nbe nisale
Ibi esin ta o ba momode lo, esin ibe, eto ibe, yio pare ni
Ibi asa ta o ba momode lo, asa ibe, Ilana ibe, yio pare ni
Ke ranti pe, owo omode koto pepe - Tagbalagba kowo kengbe
Ke ranti pe, owo omode koto pepe - Tagbalagba kowo kengbe
Omode kojobi - Agba kojoye
Omode kojobi - Agba kojoye
Torina, mase bawon wuwa ibaje, ola kiipe
Sejeje Baye ba nye e
Sejeje o baye ba tura
Maa ma bawon wuwa ibaje tori araye le
Eru agba nimo ba, Micho Ade, eru agba nimo ba
Eni ba beru agba niyo tele yi pe, Eru agba nimo ba
Eru agba nimo ba
Eru agba nimo ba
Eni ba beru agba niyo tele yi pe, Eru agba nimo ba
Niyo tele yi pe o - Eru agba nimo ba
Eni ba beru agba niyo tele yi pe - Eru agba nimo ba
Eru agba nimo ba
Eru agba nimo ba
Eni ba beru agba niyo tele yi pe, Eru agba nimo ba
Eni ba beru agba niyo tele yi pe
Eru agba nimo ba