![Money (OWO)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/13/5a27236d52fb403890df3b7f26439aff_464_464.jpg)
Money (OWO) Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2018
Lyrics
Oro towo maa dasile , apa owo koni le ka
Oro towo maa dasile, apa owo koni le ka
Oro towo maa dasile, apa owo koni le ka
Oro towo maa dasile, apa owo
koni le ka
Kilape-kanuko
Owo owo
Kilafi nsoke dile
Owo owo
Kilafi nsogbe digboro
Owo owo
Kilafi ntunle aye se
Owo owo
Kinafi nbale aye je
Owo owo
Kini Keke ihinrere
Owo owo
Ife kisini gbongbo ese
Owo owo
Kini idahunsi ohun gbogbo
Owo owo
Lori owo , lori owo o
Lori owo (Micho Ade)
Gbogbo oro gbogbo
Gbogbo oro gbogbo
Oro gbogbo Lori owo ni
Money money money ee
Gbogbo oro gbogbo
Gbogbo oro gbogbo
Oro gbogbo lori owo ni
If you want to bay Ferrari ooo
Money ni
If you want to buy Bugatti ee
Money ni
Wetin be the root of sin o
Money ni
Money ni
Baba God I dey o, let money be my friend o
Owo ni buruji
Kilape turn mouth o
Owo owo
Kilafi nsoke dile
Owo owo
Kilafi nsogbe digboro
Owo owo
Kilafi ntunle aye se
Owo owo
Kinafi nbale aye je
Owo owo
Kini Keke ihinrere
Owo owo
Ife kisini gbongbo ese
Owo owo
Kini idahunsi ohun gbogbo
Owo owo
Lori owo, Lori owo
Lori owo (Micho Ade)
Gbogbo oro gbogbo
Gbogbo oro gbogbo
Oro gbogbo lori owo ni
Money money money ee
Gbogbo oro gbogbo
Gbogbo oro gbogbo
Oro gbogbo lori owo ni