![E ku ile](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/05/18d4c32c49d4491a9abb71b300c43f3a_464_464.jpg)
E ku ile Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:1984
Lyrics
E ku ile o
O kaabo
E ma ku ile oo
O kaabo
Bekolo ba juba ile o
Benni
Dajudaju ile a lanu
Benni
Bomode ba mowo we
Benni
O daju a bagba jeun
Benni
Bomode ba juba agba a roko dale
Benni
Moti seba agba ma roko dale o
Benni
E ma ku ile oo
O kabo o
Emi Micho Ade naa re o
Mo seba akoda mo juba f'aseda o
Iba kankan f'oba Eledumare
Gbogbo asaaju mo juba kibase oo
E ma ku ile oo
O kaabo o
Senior boys, senior girls,
O ya kajojo kajo jegbadun o
O ya kajojo kajo jegbadun o
Eyin lejo, emi le lu, eyin lejo
Kokoro meji pade gege se gege
Kokoro meji pade gege se gege
Senior boys, senior girls,
O ya kajojo kajo jegbadun o
O ya kajojp kajo jegbadun o
Tobaje todu, sepe lawa
Ka korin to logbon, a tiwa ni stan-by
O ya kajojo kajo jegbadun ara wa
Senior boys, senior girls,
O ya kajojo kajo jegbadun o
O ya kajojo kajo jegbadun o
Ojumo kan ara kan
Ara tuntun la gbede
Ojumo kan ilu kan o
Ilu tuntun la gbede
Eegun njo o, ojo nro,
Sigidi nworan ninu ojo see gboyen ri
Afoju lo nroyin faditi bose sele,
Ara koniitan nile alara mo gbere da
Hee
Hee
Hee
Micho Ade bi kowee ba pede
Eye tobawu ko soro
Orin tiwa ti kuro ni wasa
Baby gbo o sodi wuke
O sare somo bobo e
Loba doni wamo wamo
Lo doni tipe tipe
Ilu ndun guiter 'o gbehin,
Ojumomi si pere ode talo fa sababi o,
Micho Ade, Micho Ade
Omo 'osun latale ana
Micho Ade, Micho Ade
Talo fa sababi
Micho Ade, Micho Ade