- Genre:Gospel
- Year of Release:2025
Lyrics
Igbagbo mi duro lori
Eje at'ododo Jesu
Nko je gbekele ohun kan
Leyin oruko nla Jesu
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
B'ire ije mi tile gun
Or'ofe Re ko yi pada
B'o ti wu kiji naa le to
Idakoro mi ko ni ye
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Majemu ati eje Re
L'em' o ro mo bikun mi de
Gbati ko satileyin mo
O je ireti nla fun mi
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Gbati 'pe keyin ba si dun
A nba le wa ninu Jesu
Ki nwo ododo Re nikan
Ki nduro ni iwaju ite
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni
Mo duro le Krist'apata
Ile miiran, iyanrin ni