![Ran Agbara](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/12/ec22c80b456d42f788d3610399422224_464_464.jpg)
Ran Agbara Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Agbara Olorun
Agbara Emi Mimo
Gbat' agbara Olorun de,
Li ojo Pentikosti,
Sa if'oju s'ona pari,
'Tori won ri Emi gba.
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ki O si baptis' wa.
Ela 'han ina ba le won
Won si wasu oro na,
Opolopo eeyan gbagbo
Won yipada s'Olorun.
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ki O si baptis' wa.
A nw'ona fun Emi Mimo
Gbogbo wa f'ohun sokan
Mu 'leri na se, Oluwa,
Ti ase nin' oro Re
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ki O si baptis' wa.
Jo, fi agbara Re kun wa,
Fun wa ni 'bukun ta nfe;
Fi ogo Re kun okan wa,
Ba ti nfi 'gbagbo bebe
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ki O si baptis' wa.
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ran agbara, Oluwa,
Ki O si baptis' wa.
Ahhh ki o si baptis' wa o
Abebe ni oh
Ki O si baptis' wa
Ki O si baptis' wa
Ki O si baptis' wa
Ki O si baptis' wa
Agbara Olorun
Ti ko ni abula