Sa Gbekele Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Gba t'a b'Oluwa rin
N'nu 'mole oro re
Ona wa yio ti mole to!
Gba t'a ban se'fe Re
On y'o ma ba wa gbe
At' awon t'o gbeke won le
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
Ko s'ohun to le de
Loke tabi nile
Tole ko agbara re l'oju;
Iyemeji eru
Ibanuje ekun
Kole duro bi a gbekele
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
Ko si wahala mo
Tabi ibanuje
O ti san gbogbo 'gbese wonyi
Ko si arokan mo
Tabi ifajuro
Sugbon ibukun b'a ba gbekele
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
A ko le f'enu so
B'ife re ti po to
Titi a o fi f'ara wa rubo
Aanu ti o nfi han
At'ayo t'o nfun ni
Je ti awon ti o gbekele
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
Ni 'dapo pelu re
Ao joko ni l'ese Re
Tabi ki a ma rin pelu Re
Awa yo gbo tire
Ao jise t'o ran wa
Ma beru sa gbekele nikan
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele
Sa gbekele
Ona miran kosi
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe ka gbekele