Irapada, Itan Iyanu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Irapada, itan iyanu
Igbala okan fun gbogbo araye
Ti Jesu se fun wa
Itan iyanu ni
Itan irapada okan
Omo eniyan
Irapada
Irapada! itan iyanu,
Ihin ayo fun gbogbo wa,
Jesu ti ra 'dariji fun wa,
O san 'gbese na lor'igi.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Omu wa t'inu'ku bo si'ye,
O si so wa d'om'Olorun;
Orisun kan si fun elese
We nin' eje na ko si mo
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Eto irapada okan omo eniyan
Ni Jesu wa s'aye lati wa se
Nipa iku re lori igi agbelebu
Oti ku leekan anfani kan wa
Anfani kan soso lowa fun eniyan
Lati pada sodo Olorun
Ese ki y'o le joba wa mo
B'o ti wu ko dan wa wo to,
Nitori Kristi fi 'rapada
Pa 'gbara ese run fun wa.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Gba anu t'Olorun fi lo o.
Sa wa s'odo Jesu loni
'Tori y'o gb'eni t'o ba t'o wa
Ki yi o si da pada lae
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
A! elese gba ihin na gbo,
Jo gba ihin oto na gbo,
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Gbaa loni oh oh