Irapada, Itan Iyanu (Atunko {Reprise}) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Jesu nke
O npe gbogbo eniyan
Kan wa si ironupawada loni
Tori tire tori temi
Lo se wa ku fun eniyan
Oku ki a le pada s'odo Olorun
Ki a le di omo
Iwoba awon t'ogbagbo
Lo fun ni agbara
Lati di omo Olorun
Jesu nke pe o loni
Wa elese sun mo toosi
Je ka gbo ihinrere ti Jesu
Irapada! itan iyanu
Ihin ayo fun gbogbo wa
Jesu ti ra 'dariji fun wa
O san 'gbese na lor'igi.
A! elese gba ihin na gbo
Jo gba ihin oto na gbo
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Omu wa t'inu'ku bo si'ye
O si so wa d'om'Olorun;
Orisun kan si fun elese
We nin' eje na ko si mo
A! elese gba ihin na gbo
Jo gba ihin oto na gbo
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Ese ki y'o le joba wa mo
B'o ti wu ko dan wa wo to
Nitori Kristi fi 'rapada
Pa 'gbara ese run fun wa.
A! elese gba ihin na gbo
Jo gba ihin oto na gbo
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Gba anu t'Olorun fi lo o.
Sa wa s'odo Jesu loni
'Tori y'o gb'eni t'o ba t'o wa
Ki yi o si da pada lae
A! elese gba ihin na gbo
Jo gba ihin oto na gbo
Gbeke re le Olugbala re
T'O mu igbala fun o wa.
Jowo gba ihinrere na gbo o