![Mo F'aye At'ife Mi Fun](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/12/ec22c80b456d42f788d3610399422224_464_464.jpg)
Mo F'aye At'ife Mi Fun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Mo f'aye at'ife mi fun
Od'aguntan to ku fun mi;
Je ki n le je olotito
Jesu Olorun mi
Mo f'aye at'ife mi fun
Od'aguntan to ku fun mi;
Je ki n le je olotito
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
Mo gbagbo pe Iwo n gbani
'Tori 'Wo ku k'emi le la
Emi yo si gbekele O
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
Iwo t'O ku ni Kalfari
Lati so mi dominira
Mo yara mi soto fun O
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun m
Aye mi yo si dun pupo;
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni t'O ku fun mi
Aye mi yo si dun pupo
N o wa f'Eni to ku fun mi
Jesu Olorun mi
N o wa f'Eni oh oh
Owo owo owo