![B'aye Ba Nfa Mi](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/12/ec22c80b456d42f788d3610399422224_464_464.jpg)
B'aye Ba Nfa Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Ose o Jesu
Ose Oluwa mi
Olurapada okan mi
Mo dupe oh oh
B'aye ba nfa mi pelu ogo re
Ko s'ewu omo Olorun ni mi
Owo agbara Re y'o di mi mu
L'ojo aye mi gbogbo
Mo l'ore t'o npese f'aini gbogbo
Mo ni 'le kan loke orun giga
Wo nitori idi eyi nani
Emi se nko Haleluya.
Ose Oluwa mi
Ose o Jesu
Olurapada okan mi
Emi ko je gbagbe pe l'or' igi
Ni omo Olorun gbe ku fun mi
Ko le saiku lati gb'okan mi la
Ko tun si ona miran.
Mo l'ore t'o npese f'aini gbogbo
Mo ni 'le kan loke orun giga
Wo nitori idi eyi nani
Emi se nko Haleluya.
Ese o Jesu
Ese fun'se igbala okan mi oh
Egbamila egba gbogbo aye la
Ngo j'oloto s'Oluwa Oba mi
Ngo ma korin 'yin si
nigba gbogbo
Mo mo pe nikehin On y'o gba mi
Lati ma ba gbe titi.
Mo l'ore t'o npese f'aini gbogbo
Mo ni 'le kan loke orun giga
Wo nitori idi eyi nani
Emi se nko Haleluya.
Mo l'ore t'o npese f'aini gbogbo
Mo ni 'le kan loke orun giga
Wo nitori idi eyi nani
Emi se nko Haleluya.
Ose Olorun mi oh
Ise igbala yi
O seyebiye loju mi oh
Loju gbogbo aye
Titi aye la o ma korin
Halleluyah si yin o
Ese