![Oluwa Emi](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/12/ec22c80b456d42f788d3610399422224_464_464.jpg)
Oluwa Emi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Oluwa, emi sa ti gbohun Re,
O nso ife Re si mi:
Sugbon mo fen de l'apa igbagbo,
Kin le tubo sunmo O.
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Ya mi si mimo fun ise Tire,
Nipa ore-ofe Re:
Je ki nfi okan igbagbo w' oke,
K' ife mi si je Tire.
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Fa mi mora Oluwa oh
Olorun mi Eleda mi oh oh
Mo fe mo ero okan re
Mo fe ni ife okan re
Je ki nmo o oh
Gege b'o se mo ni oh
Oluwa mi oh oh
Eleda mi oh oh
Ere ki lo je fun eniyan
To waye ti ko mo
Olorun re
A! ayo mimo ti wakati kan,
Ti mo lo nib' ite Re,
'Gba mo gbadura si O Olorun,
Ti a soro bi ore;
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Ijinle ife mbe ti nko le mo,
Titi ngo fi koja odo;
Ayo giga ti emi ko le so,
Titi ngo fi de 'simi.
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Fa mi mo ra Oluwa oh
Fa mi mo ra Oluwa oh
Ki ma ranti agbelebu lojojumo
Fa mi mo ra Oluwa oh
Fa mi mo ra Oluwa
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Fa mi mora, mora Oluwa,
Sib' agbelebu t'O ku,
Fa mi mora, mora Oluwa,
Si b'eje Re 'yebiye.
Orin Dafidi 84