Otunba Rotimi Ajanaku (Okepopo Area) Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2017
Lyrics
Otunba Rotimi Ajanaku (Okepopo Area) - K1 De Ultimate
...
L'oke Popo x2
Oke popo x2
Eni o mon wa ko ma se dubu wa, eni o mon wa ko ma se dubu wa lona bo se iru e a te si
Oke Popo x2
Oke popo x2
Eni o mon wa ko ma se dubu wa, eni o mon wa ko ma se dubu wa lona bo se iru e a te si
Ni Lagos Island, ni mo fi r'oke popo area mi o, Tori Rotimi mi Omo Ajanaku.
Oluwa Rotimi mi Omo Victoria, Oko oyinlola baby mi omo Falana.
Ola baba Tumise, Baba Femi, Baba Fola Fola, owo Baba Feranmi
Alase Dino Group International, Alase Dino Properties. Iwo nikan na lagba laba. Alase Tunsel Farms, Ore ti Dare Dare Santana mi
L'oke Popo x2
Oke popo x2
Eni o mon wa ko ma se dubu wa, eni o mon wa ko ma se dubu wa lona bo se iru e a te si
Ko ma bami toju Alex ni Toronto mio ati Kunle Rasheed omo mi KayRash mi nko
Abiwa pele bi ori adetu mi ooo, oko Oyinlola baby mi ko gba fun e to.
Oluwarotimi ooo, omo Victoria, Alese Dino yio Omo Victoria, Omo t'Ajanaku omo Victoria, Oluwarotimi oo, Omo Victoria
Dino Dino Dino Dino Omo Victoria, Alese Dino yio omo Victoria.
Erin koja eran a un bawi, Ajanaku koja eran an f'opa lu, Omo Victoria
Oluwarotimi ooo, Omo Victoria
L'oke Popo, l'oke popo, l'oke popo ooo 3x