![Baba Seun Pupo Fun Mi](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/2B/D7/rBEeM1kcRTOAdIVXAADVHRZQP5w744.jpg)
Baba Seun Pupo Fun Mi Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2014
Lyrics
Baba Seun Pupo Fun Mi - K1 De Ultimate
...
[Instruments Play]
Toh ri mo lo'lorun leyin,
mo bo'luwa duro, okan mi bale,
kini kankan o ni se mi.
[Instruments Interlude]
Mo ma lo'lorun leyin,
mo bo'luwa duro, a ni okan mi bale,
kini kankan o ni se mi.
[Instruments Interlude]
Awa yio maa je ori, a ki yio si se iru,
awa yio maa leke sa lojo aye wa gbogbo.
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
[Instruments Interlude]
Awa yio maa je ori, a ki yio si se iru,
awa yio maa leke sa lojo aye wa gbogbo.
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
[Instruments Interlude]
Oro mi ti di joo, oro mi ti dayo ooo,
Eni ni gbagbo, a riire nibe, a joba ad'ade ogo.
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
[Instruments Interlude]
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
[Instruments Interlude]
Iwo Olohun oba, oba eleburu ike ooo,
aterere kari aye, oba to fi aye se apoti itise, kabiyesi Olorun oba, aladeluaa tan sa si, abiyamo lajoja ooo, arugbo ojo
oyigiyigi gbani gbani tan saaya ooo.
Iwo lo je emi emi ni maa se beeru,
Olorun oba, kabiyesi mo juba re ooo.
The Lord of the lords, the King of kings,
the I am that I am, the Alpha and the Omega, Bless be Thy name.
[Instruments Interlude]
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
[Instrument Interlude]
Gbogbo ibi kibi toh ota ba go si,
Olorun oba bami tu gbogbo won,
yoo Ayinde ooo
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.
Te baa leni taba baa, iwon la n bani sota
mo Ayinde ooo.
Emi ajoo ooo maa tun gbese soke wipe,
Baba seun pupo funmi nitemi.