Rora Se Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2013
Lyrics
Rora Se - K1 De Ultimate
...
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
tori ore lenikan sè lo sè lojosi to pàdà di ebi mo won ĺówó nise lo fì ori ee fa
ģbòģbò ore ti mo ba sè koni di ebi mo mi ĺówó
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
oninu ire kan lo jade nile lowuro kutukutu o n sise ee jeje jeje
nibi to gbe nlo oo o ri alaboyun kan legbe titi to n je irora to si tùń pariwo o ni ee sè anu mì nitori óĺòŕùń òbà
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
oninu ire si bo sibe o fe ŕóń alaboyun ĺówó nibi to gbe n bere to n bere or kilode iseju kan si ikeji lalaboyun bà dake
ani bi ore bà po a de ebi ģbòģbò ore ti mo ba sè òò koni di ebi mo mi ĺówó
awon ero to n koja lo oo ģbòģbò bà sare wà won bere pe kilode wipe bawo lo sè śè tì alaboyun fi dake
won bà fa óró yi tìtì won kò ra wóń o di Ile òbà
ìģbà tò de odo òbà àlàdè oninu ire bà ròjó o soro o bù sì ékun òò ò ni
rora sè rora sè anybody tì ò bà fé sè ore
rora sè rora sè ooo anybody tì ò bà fé sè ore
kama ma mu óró yi gun òò ani ejo elejo
óró ólóró laye nbi kò ni di ebi mo mi ĺówó
bi ore bà pó a di ebi wàsìú àyìnde òò
ģbòģbò éyìn asè ore laye nbi òrè ò ni su wà sè oo
ko pe ki a ma se ore sugbon ka fì eyi kogbon
aseyinwa aseyinbo oninure óĺòŕùń lo kò yó
aseyinwa aseyinbo oninure óĺòŕùń lo kò yó
abi éé òò rì
oninure óĺòŕùń lo kò yó
niwaju òbà àlàde
oninure óĺòŕùń lo kò yó
ani bi ore bà pó à dì ebì òò
oninure óĺòŕùń lo kò yó
òrè sisè iyen sà lò pè
oninure óĺòŕùń lo kò yò
sugbon ģbòģbò eyi ti òò di ebi óĺòŕùń làwà nbé laye nbi
oninure óĺòŕùń lo kò yò
sugbon òrè ti òò di ebi momi lòwò òò baba ko gbàmì oo
oninure óĺòŕùń lo kò yó
ore ti o di ebi mo mi ĺówó óĺòŕùń gba mi nbé àmìń
oninure óĺòŕùń lo kò yó
oninure óĺòŕùń lo kò yó