![Olorun Mi](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/2B/DE/rBEeM1kcU3SAcUzJAAC6GZPevNE721.jpg)
Olorun Mi Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2008
Lyrics
Olorun Mi - K1 De Ultimate
...
Ôlôhun mi o (Baba o se)
Ôlôhun mi o (Baba o se)
B'ęru ba dupę ore ana, a gba nlanla
Tor'Ôlôhun o fę ohun meji kôja ôpę
Ôlôhun mi o (Baba o se)
Mo dupę Ôlôhun mi o (Baba o se)
T'ęru ba dupę ore ana, a gba nlanla
Tori Ôlôhun o fę ohun meji kôja ôpę
Tori mo r'ôwô ikę Ôlôhun (Mo ri ninu isę mi)
Mo ma r'ôwô ikę Ôlôhun (Mo ri ninu isę mi)
Jiję, mimu nirôrun (La se n dupę f'Ôlôhun)
Jiję, mimu nirôrun (La se n dupę f'Ôlôhun)
Ęni ba m'ore Ôlôhun o... t'o ba m'ore Ôlôhun o... t'o ba m'ore Ôlôhun o, ko tu kękę ijo s'ilę oya o
M'ore Ôlôhun
M'ore Ôlôhun...
Ko tu kękę ijo s'ilę oya
Ęni ba m'ore Ôlôhun o... t'o ba m'ore Ôlôhun o ko tu kękę ijo s'ilę oya o
M'ore Ôlôhun
M'ore Ôlôhun...
Ko tu kękę ijo s'ilę oya
Oduro f'isę t'o n se s'ilę, wa jo o n ki
Ôkôyawo f'isę t'o n se s'ilę, wa jo n ki
Ôkôyawo f'isę t'o n se s'ilę, wa jo n ki
Ijô o ba fę segbayawo bawo lo se a jo o
Ani Ijô o ba fę segbayawo bawo lo se a jo o
Kiamôsa yaa dide nlę k'o mujo iyawo, ijo oge (Bęręmôlę k'o mujo oge)
Kiamôsa yaa dide nlę k'o mujo iyawo, ijo oge (Bęręmôlę k'o mujo oge)
Ani kiamôsa yaa dide nlę k'o mujo iyawo, ijo oge (Bęręmôlę k'o mujo oge)
O d'abô ôja o... o d'abô ôja... mo l'o d'abô ôja o
S'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de (O d'abô ôja o)
S'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de o (O d'abô ôja o)
S'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de o (O d'abô ôja o)
Ti n ba se bayi (Ara m'e da)
Ti n ba se bayi (Ara m'e da)
Ti n ba se bayi (Ara m'e da)
Ę ti se s'ôrô mi si
Ę ti se s'ôrô mi si
Onipele, alabaja ę ti se s'ôrô mi si o
Ę ti se s'ôrô mi si
Ę ti se s'ôrô mi si
Onipele, alabaja ę ti se s'ôrô mi si o
Ę ti se s'ôrô mi si
Ę ti se s'ôrô mi si
Onipele, alabaja o ę ti se s'ôrô mi si o
Ę ti se s'ôrô mi si
Ę ti se s'ôrô mi si
Onipele, alabaja ę ti se s'ôrô mi si o
O d'abô ôja o... o d'abô ôja o
S'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de (O d'abô ôja o)
Eko, k'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de o (O d'abô ôja o)
K'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de o (O d'abô ôja o)
K'aye mujo wa t'oku, o di bi n ba de o (O d'abô ôja o)