Oonirisa Ogunwusi Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2017
Lyrics
Oonirisa Ogunwusi - K1 De Ultimate
...
Yoruba Mo oun to da
won Mo oun to da
won l'asa to wunmi oo
lo se wu mi Lori o
wipe Mo je Yoruba
eyin oba lade lade, eku amojuba o kabiyesi Onirisa ooo
Yoruba Mo oun to da
won Mo oun to da (x2)
won l'asa to wunmi oo
lo se wu mi Lori o
wipe Mo je Yoruba
eyin oba lade lade, eku amojuba o kabiyesi Onirisa ooo
Kabiyesi
Oba to to bi aro, Oba rere bi Osu
aro ba fin loba pa, Mo wole Mo pagun mowo (x2)
Adeyeye Oba ooo
Oba ooooo
Oba Adeyeye Oba ooo
Oba ooo
Kabiyesi lemi oo
Enitan Oba Adeyeye e
Omo Ogunwusi oo
kabo so ri aleefa, gbogbo wa lon ki Oba
B'oba ba ti dega, onikaluku won a wole fun Oba ni, aroba fin loba pa
Adeyeye Oba ooo
Oba ooooo
Ewi fun won ni ile alara, Eso ni ile ajero
Arole Oduduwa Ojaja ti de, Oba Adeyeye ooo
sekere, agogo oun la Jo nle Oba aaa (x2)
eyin aroba fin esora ke ma jiya
sekere, agogo oun la Jo nle Oba aaa
eyin aroba fin esora ke ma jiya
sekere, agogo oun la Jo nle Oba aaa
eyin aroba fin esora ke ma jiya
sekere, agogo oun la Jo nle Oba aaa
Ka'abo sile ooo
ka'abo sile ooo
arole oduua
ka'abo sile oo
arole oduua o
ka'abo sile oo
Kabiyesi, Oba enitan o Adeyeye omo to' gunwusi, ojaja the second, Onirisa ilu Ife ooo
arole oduua o
ka'abo sile oo
Oba Adeyeye
ka'abo sile oo
Deyeye Omo Ogunwusi
ka'abo sile o
aregbesola Raufu foba he
ka'abo sile oo
Desoji, oko bidemi foba he
ka'abo sile oo
igba e, a tuwa Lara
ka'abo sile oo
asiko yi, a tuwa Lara
ka'abo sile oo
Elegushi ni koba
ka'abo sile oo
Oba Ademola saheed oo
King gushi ni koba
ka'abo sile oo
Aremo oniru
pela kushi ni koba
ka'abo sile oo
arole oduua o
ka'abo sile oo
mo Tara Onirisa
Moki won ni Iwo ile
Iwo omo odo Oba
omo Oba to ni mere
Moro e tosi
owo nla nla, eru wewe ni won fi dele ni Iwo
Aku amojuba oba tuntun
Aleyeluwa
Oba Adewale Akanbi Rasheed
Iwo mo ki yin
oluaye Fuji
ogbo ato toba ni se ooo
toba ni se
ka'abo sile oo
ka'abo sile oo
gbogbo ikorodu oriuu
omo eluku mede mede
eluku mede mede
umale omo afeleja
aku amojuba ayangburen tuntun
Oba dewale, Oba sotobi o
ni ikorodu
ka'abo sile oo
ka'abo sile oo
arole oduua o
asiko yin atuwa Lara
ka'abo sile oo
igba yi atuwa Lara
ka'abo sile o
asiko yi atuwa Lara
ka'abo sile ooo
ka'abo sile oooooo