- Genre:Fuji
- Year of Release:2008
Lyrics
Woro - K1 De Ultimate
...
Beat…..
Esin to siwaju ‘nlo gbafe, Esin to siwaju ‘nlo gbafe o
Eyin te n seto, e gbefe fun
Igba funfun loromi, Igba funfun loromi o
Eni ba mowe, ko ka lo.
Repeat….
Ori omo lo sho’mo
Iya ‘ti baba omo lo ko mo yo o
Ota o gbero wipe koda
Igba funfun loromi, Igba funfun loromi o
Eni ba mowe, ko ka lo.
Repeat…..
Asalamu alekun ooo, gbogbo ekoo fediraaa ooo x2
Olowogbowo se ti e, o perengedeeee
Isale offin se ti e, o perengedeeee
Isale eko se ti e, o perengedeeee
Epetedo se ti e, o perengedeeee
Lafiaji se ti e, o perengedeeee
Campus o se ti e, o perengedeeee
Igi gbogbooo, Igi gbogbo oni showo o
Oto ni tobi,
Olowogbowo oto,
Okepopo oto
E r’okofaji b’e d’onola o
Kaabo oooo, kaabo X2
Okofaji taajo de o
Kaabo o
Mok’eni, Mok’eji, Mok’eta
Oro gbenu oloro ma le so
Kaabo ooo, kaabo x2
Okofaji taajo de o
Kaabo o
Omo eko fedira mi o
L’okunrin L’obinrin gbogbo wa
As’odun odun yii, a o s’emi si tomo tomo
Gunugun ki p’odun je o
Al’arodun odun yi l’owo, l’omo, l’alafia ara o,
gbogbo wa la o se pupo odun laye o, ayinde o
Igi gbogbooo, Igi gbogbo oni showo o
Oto ni tobi,
Olowogbowo oto,
Okepopo oto
E r’okofaji be d’onola o
Kaabo oooo, kaabo x2
Okofaji taajo de o
Kaabo oooo