![Ara- Edide](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/2C/BC/0252eefa0a8d4df1b95d9c9c03d97ddd_464_464.webp)
Ara- Edide Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2008
Lyrics
Ara- Edide - K1 De Ultimate
...
Awa de de de de de
Awa de
Awa la n k'ômô l'ede, awa de
O ri bi n se n wi
B'ôlôgbôn ba se bi ęni gbôn, omugô t'o ba wa nibę a ma ba wôn ka lô ni
Awa de de de de de
Awa de
Ayinde l'akômôl'ede, awa de de de de de
Isôla Ade ômô Amusa
Raufu ôkô Surajatu mi maa gbô ni Kutônu
Awa de de de de de
Awa de
Awa la n k'ômô l'ede, awa de
Awo ti Wumiu, awo Alao Latifu
O lo m'ęni o s'edi bębęrę
Isôla ômô Adetunji
K'a f'ilękę s'idi ômô ęlomin
Ayinde Wasiu mi, tęni n tęni
Iwô gbô gbô gbô gbô gbô
Iwô gbô
S'o r'igba ti mo wa l'ômôde
Wôn ni b'ômôde o le nkan o, nkan nla ti le
Iwô gbô gbô gbô gbô gbô
Iwô gbô
Tori iya mi, baba o wôn bi mi da
Emi gangan mo tun tunra bi
L'orukô n se nga si
Iya mi, baba o wôn bi mi da
Emi gangan mo tun tunra bi
L'orukô n se nga si
Ę wo o...
Bode the way maa gbô bi mo se n k'ôrin mi, ôkô Bôlaji
Iyęn mama k'o f'osi... l'Amęrika mi, ni love island
Eyan Niyi Ayęni bi * ôkô Debby
Awo Sikiru ômô Ęnifęni o... ôkô Ade mi kunbi Sębi
Ę ku itôju mi ômôgbôlahan mi, ômô Anifowose, ę ri
Iya mi, baba o wôn bi mi da
Emi gangan mo tun tunra bi
L'orukô n se nga si
Iya mi, baba o wôn bi mi da
Emi gangan mo tun tunra bi
L'orukô n se nga si
Iya mi, baba o wôn bi mi da
Emi gangan mo tun tunra bi
L'orukô n se nga si
Ba n da kasa f'ômô Anifowose o (Eh... ah, eh)
Ba n da kasa f'ômô Anifowose o (Eh... ah, eh)
Ba n da kasa f'ômô Anifowose o (Eh... ah, eh)
Ba n da kasa... kasa... kasa...kasa... kasa... kasa... kasa... kasa... kasa... Dakun da kasa f'ômô Anifowose o (Eh... ah, eh)
Ę ba n da kasa f'ômô Anifowose o (Eh... ah, eh)
M'e le s'aijo fuji o
M'e le s'aijo fuji o, tori alujo pô pupô nibę (M'e le s'aijo fuji)
M'e le s'aijo fuji o
M'e le s'aijo fuji o, tori alujo pô pupô nibę (M'e le s'aijo fuji)
Isęyin egungun tigbala de o
M'e le s'aijo fuji o
M'e le s'aijo fuji o, tori alujo pô pupô nibę (M'e le s'aijo fuji)
Toripe o n dun, o n dan o
O n dun, o n dan o
Ilayi Eledumare mi, Baba ma se fi kikan si
M'e le s'aijo fuji o, tori alujo Ômôgbôlahan (M'e le s'aijo fuji)
Tori alujo Ômôgbôlahan (M'e le s'aijo fuji)
Tori alujo Ômôgbôlahan (M'e le s'aijo fuji)
Tori alujo Anifowose (M'e le s'aijo fuji)
Ômô Môtoyôsi Monsuratu (M'e le s'aijo fuji)
'Môtoyôsi, Barrister Lawyer (M'e le s'ai jo fuji)