
Igbayi Ti Adara Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2017
Lyrics
Igbayi Ti Adara - K1 De Ultimate
...
(instrumentals)
Igbayi tí dara o dun
B'oluwa ti fe ooo
Igbayi tí dara o dun
B'oluwa ti fe
ọlọrun Ọba lóni igba
Eni ba wun Olórun lọ n gbé lé lọwọ
Mo sọpẹ témi Omogbolahan mi Ara ba mi bi Ọba orin
Ẹni èèyàn bàa n be lẹyìn fún oó
Ìyẹn ko ma yọ máa jo
Mo sọpẹ idi ti o baje
Mo sọpẹ atẹlẹsẹ to n tena
ọpẹ mi lojoojumo ayé
me lè sayi dupe dupe dupe
Igbayi tí dara o dun
B'oluwa ti fe ooo
Igbayi tí dara o dun
B'oluwa ti fe
Afẹfẹ n fẹ, Ìjì n ja
Ile n su, Ilẹ n mọ
Ojo n ro, Òrùn n ran
Sugbon kinikan lo dami loju
iji o ni já kò dá omi inu agbọn nù lailailai
aṣọ eledumare ni aso ọlọrun Ọba ni
oromi Dade òkín oooo
kìí ṣẹ feyekeye eeri bíi .