![Olorun Sanu Fun Mi](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/0B/68/rBEeM1hRW8mAF54KAADE-w3PzUQ475.jpg)
Olorun Sanu Fun Mi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2011
Lyrics
Olorun Sanu Fun Mi - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
niti ishaju ,oluwa fagbarare han .(2*)
soro Ashe sinu aye mi ,
soro iyanu sinu Ile mi
agbara igbani owa sibe sibe oo.
oluwa fagbarare han .
(repeat).
emi yo gbe oju mi sorioke wonni
nibo ni iranlowo mi yio ha ti wa
iranwo mi yio Todo Jesu wa
alagbara (2*)
oludamoran
Abanidaro (2*)
ore ti kin Dani
ohun logba gba
ogba gba tin gba alayilara
Niti ishaju .......
oku rio osa
jordani pada seyin
ni kutu kutu ni won jade lo
Ogun armoni won a ku subu
josafati ko gbe Ida soke
sugbon Ogun olorun lojafun
ogbe Inu ile tafa soke
tolagbara , tolagbara Lori imolu ota
tolagbara Lori Omi ati eje
tolagbara Lori Emi gbo gbo
Tani kio beru ree (2*)
oba orilede gbo gbo
Niti ishaju.......
zacheru rioo
igbala wole ree .
Omo jairu nko.
oji dide ninu oku
iseti aso Jesu
o wo obinrin oni sun eje San
oba to ku to Jin dee
Jen ri owo agbara ree laye mi
mo gbagbo (3*)
tinu tinu mi oluwa mo gba o gbo
onikin maberu
Tori oti segun aje
onikin mafoya
ota oni bori mi
mogba o gbo oo
mogba....
mogba gbo baba aa
ninu eri ree
Iwo lo Le se tiwa aye mi
baba ma Fi mi sile
mogba gbo....
Iwo lo Le soro mi dayo
mogba gbo ..
Fi ola re yi mi ka
mogba gbo... tinu tinu mi oluwa mo gba o gbo
beat
lati ti ko se
loro re tin se Iyanu
baba lati ti ko se
loro ree tin se Iyanu
okukun gba Ile aye kan
aye SI wa lai nitun mo
opase ki imole kio wa
itura de okukun parada .
beat
oluwa agbara fohun
bi oro oke Sina
awon aje gbohun ee
won SI ho fun iberu
beat
baba fagbarare han
fagbarare han
Kaye Le mo
pe Iwo ni baba ......(4*)