![Jesu Lori Sun Ayo](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0B/9E/rBEeMVhRWTuAdNrTAACv9-laI88970.jpg)
Jesu Lori Sun Ayo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2009
Lyrics
Jesu o iwo lorisu ayo o
Jesu kristiawo iwa yeye ti de
Orison iye fun okan gbogbo
Titi aye ni wo ma gbe o ja
INSTRUMENTAL
Jesu o iwo lorisu ayo o
Jesu Kristi awo iwa yeye ti de
Orison iye fun okan gbogbo
Titi aye ni wo ma gbe o ja
Ile aiye o o kun fun isoro
Igbokegbo do lo gba ile aye kan
Ona miran ko si lati ri isimi
Jesu Kristi lorun ayo
Jesu o iwo lorisu ayo o
Jesu Kristi awo iwa yeye ti de
Orison iye fun okan gbogbo
Titi aye ni wo ma gbe o ja
Opo eda wa to fi owo se olorun
Uhn wow o osa ile aye yi ma ya
Won ti gba gbe ine pe won o mu ohun kan wa aye
Imu le mo fo ile aiye asan ni
Jesu o iwo lorisu ayo o
Jesu Kristi awo iwa yeye ti de
Orison iye fun okan gbogbo
Titi aye ni wo ma gbe o ja
Nigba idamu tabi ninu isoro
Baba alawo ile aye ko le gba o
Sato jesu oni majemu ayo ninu ife oro re a da yo
Jesu o iwo lorisu ayo o
Jesu Kristi awo iwa yeye ti de
Orison iye fun okan gbogbo
Titi aye ni wo ma gbe o ja
Oluwa damilare o da mi lare
Oluwa damilare o dami lare
O segun fun mi segun fun mi
Mo lo tip e se fun mi o pese fun mi
O pa mi lerin ayo erin ayo
O fi jemi laya o fi jemi laye
Pe nigba isoro nigba ipan ju
Ni gba I damu kin ma se mika n rara
Gbo mi kan gbo mi kan
Gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi ka gbo mi kan
Oro re a dayo
Gbo mi kan gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan gbo mi kan oro re a dayo
Gbo mi kan oro re a dayo