
Gbo Ohun Alore Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2011
Lyrics
Gbo Ohun Alore - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
Gbo ohun, Gbo ohun, Alore ndun
To kede, ihin rere ayo fun wa
Jesu olugbala aye fere de
A de o, A de o, Irapada wa
Gbo ohun, Gbo ohun, Alore ndun
To kede, ihin rere ayo fun wa
Jesu olugbala aye fere de
A de o, A de o, Irapada wa
Adam akoko, alaye okan ni
Adam Igbeyin, eni isoni di alaye
Majemu tuntun lo so wa domo
Ninu jesu, eri iye aye tuntun
Gbo ohun
Gbo ohun, Gbo ohun, Alore ndun
To kede, ihin rere ayo fun wa
Jesu olugbala aye fere de
A de o, A de o, Irapada wa
Okunkun, oru dudu bo ile aye
Okunkun, biri biri bo eniyan
Igba na imole irawo, omo maria
Wa lati laja larin eniyan ati olorun
Gbo ohun, Gbo ohun, Alore ndun
To kede, ihin rere ayo fun wa
Jesu olugbala aye fere de
A de o, A de o, Irapada wa
Ipe ndun o, si ironu piwada
Mu iwa ika, ese ku ro lana re o
Ya kuro, lana to ya si iparun,
Ki ale ka o ye o, ni gba ti jesu ba de
(Gbo ohun)
Gbo ohun, Gbo ohun, Alore ndun
To kede, ihin rere ayo fun wa
Jesu olugbala aye fere de
A de o, A de o, Irapada wa
Igbagbo mi duro lori oro re
Otito ni majemu eje re
Aye le sipo, ki orun folo
Igbagbo mi duro lori oro re
Otito ni majemu eje re
Ore le dota o, ki osan doru
Igbagbo mi duro lori oro re
Otito ni majemu eje re
Idanwo lede o, ???
Igbagbo mi duro lori oro re
Otito ni majemu eje re
Igba ti a mi robi, le ni wa Lara
Sugbon lai pe, a o ki wa ku ewu
???? Ireti e duro
E duro o, nibo odi agbara
Gbo gbo onigbagbo o
Tiwon reti ibimo jesu
Gbo gbo onigbagbo o
Tiwon reti ibimo jesu
E di amure ???, ki e ma sona
Ijoba orun ti di afagbara wo
Awon Alagbaka lon fipa wo
Fi agbara fun mi, kin le rin ni ona yi
………
Mo sa di o o baba
Alagbawi gboro mi wo
Bawo ni mio se le la
Jesu, wa ran mi lowo
(Baba mo sa di o)
Mo sa di o o baba (alagbawi o)
Alagbawi gboro mi wo
Bawo ni mio se le la
Jesu, wa ran mi lowo
Leyin ogofa odun, eli di eni itanu
Mose gbiyanju titi, leyin opo Ìṣe iyanu
Owo ile ileri yii lokere
Ko ma le de canaani
Mo sa di o o baba
Alagbawi gboro mi wo
Bawo ni mio se le la
Jesu, wa ran mi lowo
Saul oba israeli lojo ojo si,
Oga, orewa pupo
Ogba ore ofe eni ami ororo
Nigbati samueli yan loba
Sugbon esu de ode re, osubu, okuna ogo olorun
Mo sa di o o baba
Alagbawi gboro mi wo
Bawo ni mio se le la
Jesu, wa ran mi lowo
…………..
Motigbagbo fun ogun odun, Ko to gbon
Moti sin olorun fun odun ogbon, ofo ni
Iranlowo Oluwa lo le muni duro,
Dimimu o jesu, kin ma subu lona yii
Ran mi lowo baba,
Di mimu o, Jesu
Alagbawi, ran mi lowo
Ran mi lowo baba,
Di mimu o, Jesu
Mu mi duro di opin ajo
Duro timi olorun ayo
Fi agbara fun mi, ma je nbaye lo
Emi yio gboju mi soke si baba
Ni bo ni iranlowo mi yio ha ti wa?
Iranlowo mi yio ti owo Oluwa wa,
Oba ayo, oba to le ran mi lowo
Iranlowo mi yio ti owo Oluwa wa,
Oba ayo, oba to le se ohun gbogbo
Ran mi lowo baba,
Di mimu o, Jesu
Oluwa ran mi lowo
Ran mi lowo baba, (Jesu, di mimu o)
Di mimu o, Jesu
Mu mi duro di opin ajo
Duro timi olorun ayo
Fi agbara fun mi, ma je nbaye lo
Tori mo fe lati rin ninu emi, ki ma se se ife ara
Tori ara lodi si emi, emi mi yio se ife baba
Oluwa ran ni lowo
Ran mi lowo baba,
Di mimu o, Jesu (Jesu, ran mi lowo)
Ran mi lowo baba,
Di mimu o, Jesu
Mu mi duro di opin ajo
Duro timi olorun ayo
Fi agbara fun mi, ma je nbaye lo