![Jesu Ni Balogun Oko](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/0B/43/rBEeM1hBWmKACXZfAADY9yY6zu4725.jpg)
Jesu Ni Balogun Oko Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2012
Lyrics
Jesu Ni Balogun Oko - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
Jesu ni balogun oko, e mase je ka foooya, olu toko wa ni Jesu, e mase je ka foooya, e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Gba ti gbi aye yi ba n jaaa, lo rokun ati nile, akoko nbe ti o daju, lodo Olugbala wa, e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Metalokan alagbara, da bobo awa omoore, lowo ategun ati 'ji, je ka wa ka le lu yah. e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si. dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si. Dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si.