
Hossana Iye Halleluyah Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2011
Lyrics
Hossana Iye Halleluyah - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
Fiyin foluwa iwo okanmi
Fayo sin oluwa iwo okan mi/2x
Olurun oludumare oma se
Oba ori aye gbogbo
Iwo ni iyin ye
Fiyin foluwa iwo okan mi
Fayo sin oluwa iwo okan mi
Oba mimo to moye irawo
Iwo lo to kawa o fiyin fun
Olorun ayo oba toto gbani
Fiyin foluwa iwo okan mi
Fayo sin oluwa iwo okan mi
Oba toda ye ati ekun re
Lo fi eniyan joba Lori ise re gbogbo
Fiyin foluwa iwo okan mi
Fayo sin oluwa iwo okan mi
Intrumental