![Jesu Yio Joba](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0B/9E/rBEeMlhRWp-ABEaiAADvqsNL_nQ595.jpg)
Jesu Yio Joba Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2011
Lyrics
Jesu Yio Joba - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
instrumental
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
instrumental
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
instrumental
gbo ohun alore to nke si o
wipe pada alapehinda omo
wa gba imuse ileri tao fi fun o.
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
instrumental(jesu tii joba) 2ce
baraaye Fe baraaye ko
jesu ti joba.
jesu yio joba ni gbogbo agba'ye
a gba wa la Kuro loko eru ese ore kalo oo
ka lo ba jesu wole mimo
ile alayo ologo aidibaje
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
instrumental
aiye yio pin orun yio koja
awon alagbara yio ba fun iberu
onigbagbo yio gba idalare
ni'le itura didan ta o
f ade wa lele
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
instrumental
eyin ara ekokiki re
ese loba lori agbaye
owo egbegberun ogun orun
ni yio kede dide oluwa
Jesus yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agba'ye
Jesus yio joba ni gbogbo agba'yee
emura lati pade ree.
beats
instrumental
to ba deeee
to ba deeee
Ara mi oo to ba dee
to ba deeee
alikama la o ko sinu aba o
epo la o fina sun patapata
ewo lo yan ore jewo ara re
oo ba jewo ara re
ewo lo yan ore jewo ara re
ore jewo ara re
ewo lo yan ore jewo ara re
iye tabi iku
ewo lo yan ore jewo ara re
imole tabi okunkun
ewo lo yan ore jewo ara re
ore ewo lo yan o
ewo lo yan ore jewo ara re
paradise tabi ina
ewo lo yan ore jewo ara re
ile didan tabi ewon
ewo lo yan ore jewo ara re
jesu lona tooro iye
ewo lo yan ore jewo ara
oba to ku fun o
ewo lo yan ore jewo ara re
jesu to ye fun mi
ewo lo yan ore jewo ara re
oba to n fun ni ire
ewo lo yan ore jewo ara re
ohun lo n fun ni laayo
ewo lo yan ore jewo ara re
o mo oni , o mo ola re
ewo lo yan ore jewo ara re
jesu yio joba araye eyo
ekede re fun gbogbo agbaye
jesu yio joba ni gbogbo agbayeeeeeee