Last time Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Mo ni accident kekere kan for dis year
Mo ti di kokumọ for d rest of dis year
Kekere loku tin ba kan lẹsẹ
Mo ti ẹ ṣi ṣọpẹ temi for dis year
Ani ko ṣọpẹ ti ẹ
Mo ṣọpẹ temi
Nkan to ṣẹlẹ si mi last time
O kọja oye mi
Ani ko ṣọpẹ ti ẹ
Mo ṣọpẹ temi
Nkan to ṣẹlẹ si mi last time
O kọja oye mi
Oju ri ẹnu o le sọ
Ẹ dẹ le gbọ nkan kan afi elehi tinba sọ
Many many things wey don sup
Sibẹ sibẹ Paul ni Saul
This very last time men o ka mi lara
Men o ka mi niṣan
Can't walk for days i might go crazy
I go keep my nerves werey tun le bumijẹ
Mo ṣeṣe lori ọkada wọn tun ji phone mi
Kosi owo sub men i av to sell my dog
Dat's my bestfriend buh mi o ni choice
Gbogbo mindset temi nothing buh joy
Every seconds kẹdẹ re ọlọjọ nka ọjọ
Medical bills from Monday to Sunday
Pẹlu gbogbo staff wọn wọn gbọ payan
Mo ni accident kekere kan for dis year
Mo ti di kokumọ for d rest of dis year
Kekere loku tin ba kan lẹsẹ
Mo ti ẹ ṣi ṣọpẹ temi for dis year
Ani ko ṣọpẹ ti ẹ
Mo ṣọpẹ temi
Nkan to ṣẹlẹ si mi last time
O kọja oye mi
Ani ko ṣọpẹ ti ẹ
Mo ṣọpẹ temi
Nkan to ṣẹlẹ si mi last time
O kọja oye mi