
Dahun Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2021
Lyrics
Tinba ṣe lu koma Dahun
Boba ṣelu koma Dahun
Bẹba ṣelu koma Dahun
Taba ṣelu koma Dahun
Tinba ṣe lu koma Dahun
Boba ṣe lu koma Dahun
Bẹba ṣe lu koma Dahun
Taba ṣe lu koma Dahun
Koseyan kan lẹhin Ọlorun
Ki lo wa ṣẹlẹ ti o ti Dahun
Gboju mi soke si iwọ Ọlọrun
Nibo ni iranlọwọ yi o a ti wa
Nigeria lowa my nigga ko wake up
A bo nsun
Abi on sun, Ago marun ti lekan
Kowo pọ biti Deji Ọlamilekan
No be today Ọlohun o ti pẹ gan
Ṣa akoko ni o ti to abi mio ti ṣiṣẹ kara kara ni
Ṣekin ṣe mo ti gọrami nigbayẹn to yẹn kin japa ni
Gbese pọ o fẹ pami
Ọpẹ lọpẹ uusssss lara mi
Kin lowo kin lọ ṣe medical Check up
Ko ma Jẹ pe o un gan loma lọ Fuck up
Ni Jọ wo gan lowo mi wa fẹ Stack up
More reason fun mi niyẹn lati Buckle up
Ẹni robi romi koma ba ku lọ
Olowo o lọ ra omi ninu Quilox
Lai ṣepe ko si omi ninu Borehole
O le dẹ ya photo ko di Alakada
Eyan Toyin Aimahku Alakada
Abi kin ma fẹsẹ mi ṣa lọ Canada
Kin sọrami di nepa to ma n ka wire
Oriṣiriṣi lori ori fẹ bend
Awọn kan sọ funmi pe mo ti ment
Kinto rowo mo ma ma n po cement
Aye tawa bai ati ri fifty cent
Ole koko afibiti oju ẹjaa
Koluwa ko gba wa ni oo
Ogẹdẹ towa lẹyin kuleyin
Tinba ri o pọn ko pọn mo ma ka
Tinba ṣe lu koma Dahun
Boba ṣelu koma Dahun
Bẹba ṣelu koma Dahun
Taba ṣelu koma Dahun
Tinba ṣe lu koma Dahun
Boba ṣe lu koma Dahun
Bẹba ṣe lu koma Dahun
Taba ṣe lu koma Dahun