Onile Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Who dy we dy knock for my door kọkọkọ
Matagbamọlẹ in da building lord knows mi no go open dat door kokoko
Who dy we dy knock for my door kọkọkọ
Matagbamọlẹ in da building lord knows mi no go open dat door kọkọkọ
Orin la kan n fa a fa gobe
Tẹba fa gburu gburu a fagbo
Laipẹ all my pain shall fly away
Mi o gbe jawa mi o dẹ wa bayin ṣere
Ere la fi ọmọ ayo ṣe
Erekere niyẹn a ni lati fi iyọ si
Ọmọ alai ni baba opponent ni everybody
Fear nobody respect everybody
Gang Gang Gang ninu Gang Gang
Lyrical swordsmanship eyan Wu Tang
Gbemidebẹ ẹsẹ mi o balẹ mọ
Ki ni ago sọ tẹ ti lọ n palẹ mọ
Ohun re ọmọ to fi ori ọka wọ imu
Loju orun o un jẹun pẹlu alujọnu
Wasted effort Issa No no
On your marks get set go go
O ni bi malu ṣe yawere to
To ba ri were wa ri pe o yawere to
Who dy we dy knock for my door kọkọkọ
Matagbamọlẹ in da building lord knows mi no go open dat door kokoko
Who dy we dy knock for my door kọkọkọ
Matagbamọlẹ in da building lord knows mi no go open dat door kọkọkọ
Orin la kan n fa a fa gobe
Tẹba fa gburu gburu a fagbo
Laipẹ all my pain shall fly away
Mi o gbe jawa mi o dẹ wa bayin ṣere