
As a guy Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Wọn n ja nile keji ko le kan wa
Tori tiwa gan wa lara wa
Ẹ sọ fun alariwo pe awa o jẹ yẹpẹ
Lalẹ friday ọgẹdẹ ti pọn dẹdẹ
Now is about time
Nkan to ba ti ya ko kin pẹ mọ
Ikilọ kọ buh a quick reminder
Cindarella to l'oun mamacita
Gatz to show ur face before d story change
Ṣe iyẹn ma work gotta find a way
Ṣo ti ye ẹ wat am trying to say
Ibi ti mo ti wa dẹ fuckin far away
Toyẹ koma mu agbo o lọ n order champagne
Buh eyi wunmi o wun ọ OT yẹn ṣi gum
OT yẹn ṣi gum
OT to gum
As a guy
As a guy
Y u go dy smile
Kilo funny
Everything ti cost
As a guy
Y u go dy smile
Kilo funny
Everything ti cost
As a guy shey u know dis thin ẹyin lohun
To bati balẹ o ma n fọ ni
So watch your tongue
Awọn kan o kin pari ija
Buh a wa n tiwa a o le ma bolowoja
Tinba lo n bolowo ja ki ni awọn ọmọ mi majẹ
Mo ni ifẹ iyawo mi nkan to ba tifẹ ni mo ma ba fẹ
O n bọ o n bọ awọn la n dẹ de
Semi jẹjẹ toripe mo sẹsẹ de
From YABAleft mo ri awọn patient
Wọn kan wave from right to left
As a guy mo ya mellow eh mo mellow
Nkan to n du ni lo n pọ lọrọ ẹni seh
As a guy
Y u go dy smile
Kilo funny
Everything ti cost
As a guy
Y u go dy smile
Kilo funny
Everything ti cost