
Setemi Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Kakaki Ilẹ ku ilẹ a ṣa
Ọmọwọnuọla sa ko wa gba
O ma tan wifi ẹ kale connect
Oluwa lo mọ next
Comment Tu T'appelle
Toba ṣetemi o le ma rọkọ fẹ
To ba ṣetemi o le ma raya fẹ
Toba ṣetemi o le ma rọkọ fẹ
To ba ṣetemi o le ma raya fẹ
Ile ọba to jona ẹwa lo bu si
Malu o ṣe fi ẹnu fọn
Ẹran to yiyiyi ni namọ
Ina nepa yatọ si ti sọnmọn
Epe epe ni pole
Abọ abọru bọye
To ba gbọ gbe gbe gbe
Pọpọri Pọpọri Sweet Melanin
Ti ba di ẹ ni wey dy killi person
Abi na ur smile to kan n damilọrun
Ẹwọ ma care o le payan si mi lọrun
Wo fun fact
For ur matter mo le run mad
Lọtun losi kan ma attack
To ba fi mi lẹ issa n Hazard
Kakaki Ilẹ ku ilẹ a ṣa
Ọmọwọnuọla sa ko wa gba
O ma tan wifi ẹ kale connect
Oluwa lo mọ next
Comment Tu T'appelle
Toba ṣetemi o le ma rọkọ fẹ
To ba ṣetemi o le ma raya fẹ
Toba ṣetemi o le ma rọkọ fẹ
To ba ṣetemi o le ma raya fẹ