
Omotunde Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Ki lo n bọ loke ti ilẹ o le gba
Holy father aba father
Wey ur face
Ma lọ ma lọ ma ṣe no face no case
Eledumare Ọba a ji ki ọba a ji ki
Odu to di aṣiri ẹyin gan gan lawa ri
Awa de Awa de Ọmọtunde
Iṣẹ kekere plenty raba
Iṣẹ kekere for d big bag
Ibadan kini show rẹ
Ewo ni phone ẹ
Nbo lo ti kọ Phonee ẹ
O ma ni lati kọ'la s'ohun ẹ
Ohun ẹ o kito la pito
Ẹyọkan o le to
Kodẹ sure pe meji ma to
Anyways
Ki lo n bọ loke ti ilẹ o le gba
Holy father aba father
Wey ur face
Ma lọ ma lọ ma ṣe no face no case
Eledumare Ọba a ji ki ọba a ji ki
Odu to di aṣiri ẹyin gan gan lawa ri
Awa de Awa de Ọmọtunde
Iṣẹ kekere plenty raba
Iṣẹ kekere for d big bag
Anyways ironu o papọ
Isẹ logun iṣẹ eyan okafor
Agbada shatta bandle bi one yard
Broke dotman na dullard
Ohun ẹ o kito la pito
Ẹyọkan o le to
Kodẹ sure pe meji ma to
Anyways
Iṣẹ kekere plenty raba
Iṣẹ kekere for d big bag
Wavy