![Madami 1](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/07/89dc309c2bda44a3b598e3b139b58902_464_464.jpg)
Madami 1 Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Madami 1 - Emeka Indo
...
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da oooo
Iwo l'Oba Ara
Tin fin ni Dara gbogbo
Ara to wu e lo le fi wa da
Jowo wa f'aye mi Dara ire
Ewe kan ko ni Jabo
K'oba Oke ma mo si
Ara to wu e lo le fi wa da
F'aiye mi Dara ire
Tori tibi tire la da ile aye
Ojo to ro so Ewuro, lo ro si ireke
Ara to ba wu e lo le fi ni da ooo
Jowo wa F'aiye mi Dara ire
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da oooo
...........
Olorun Ara F'aiye mi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Olorun Ara F'aiye mi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
aaaaa Olorun Ara F'aiye mi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Olorun Ara F'aiye mi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Toripe Iwo L'Oba Ara
Kabiyesi Fimi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Ki n ma wa aiye bi alaiwa
Ma fi mi Dara Ibi L'aiye yi oo mo be ooo
Kabiyesi Oba Ara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Olorun Ara F'aye mi Dara
Ti yio so mi Dara F'aiye
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da
Ara ooo, ooo ooo
Ara ooo, ooo ooo
Ara Ire ni ko fi mi da oooo