![Isura](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/06/8a8649973e804be991cc87ed4c90f614_464_464.jpg)
Isura Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Isura - Emeka Indo
...
Beat##
Fa mi lowo da ni kajo ri irinajo
Irin ajo ta mo bere,ta o mopin e
Boju ba ti e yeju
Koye kowun o ye o
Inu igbago ni mariwo wun shosho oo
Ninu ofin,ninu ola,lomo pan do ro dagba o
Bi o kun ni keyan kan o
Iwo mofe rin
Ibi o lo,ni mo lor ooo
Ibi o re ,ni ma re o
Ife laisan ti se ni
Ti o mama logun o
Ife laisan ti se ni
Ti dokita o le wo
Ibi o lo,ni mo lor ooo
Ibi o re ,ni ma re o
Ife laisan ti se ni
Ti o mama logun
Ife laisan ti se ni
Ti dokita o le wo
Ibi okan eni,ba un nbe
Se be ni isura re gbe ee
Eeeba
Bo ba joun gbe eee
Mama joun gbe
Ranti ibi ta foro si
Irin ajo tamo bere
Ta o mopin e ni
Ife laisan ti se ni
Ti dokita o le wo
Ye ye ye
Lele ma pe
I na ah le
A ma eh eh eh
I love youuuuuu baby
I wanna stay with you
For the rest of my life
Without you,my life isn’t complete
I can not leave,without you Ifemi
Yeee
Oju ife nro mi
A yun Ife yun mi
O gbe Ife gbe okan mi
Yee yee wa oo
Ibi o lo,ni mo lor ooo
Ibi o re ,ni ma re o
Ife laisan ti se ni
Ti o mama logun o
Ife laisan ti se ni
Ti dokita o le wo
Ibi o lo eh eh eh,ni mo lor ooo
Ibi o re ,ni ma re o
Ife laisan ti se ni
Ti o mama logun o
Ife laisan ti se ni
Ti dokita o le wo
Mo ni pe
Ibi o lo ni mo lo
Ibi o re ni ma re oo
Ife laisan ti se ni
Ti o mama logun
Ife laisan ti se ni
Ti dokita kan o le wo ooo