![Adaba](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/07/89dc309c2bda44a3b598e3b139b58902_464_464.jpg)
Adaba Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Adaba - Emeka Indo
...
wa o wa o wa edumare !!!
wasi ibi iranlowo mi o baba
Oro aye mi iwo lomo!!
Oro aye mi iwo loye
oye o!! oye o o!!
oma ye o o
Oro mi ye o o
wasi bi irawo mi o
oye o!! oye o o
osa oke oye o
Oro mi ye o wa sibi
iranwo mi::
ma se mi latupa ton tana fun omo elomiran
sugbon ti ko ri di ara re
ma se mi ni leni ton gbo telomiran
sugbon ti ko to tare gbo
mo ma bomi Rin ogba elomiran
je ki won bo mi Rin ogba mi
kin ma sise eri jeje iri ri
ire to to ni ko Fi sise mi
iwo lo fun mi logbon imo a to ye
pe kin ma Fi somo araye loore
ma wa je kin se lansan
baba dakun ye o fere si
kin ma sise eri jeje iriri
To ri oye o!!
iwo ni alaara
Fi mi dara ire
iwo laara
iwo ni alaara
fi mi dara ire
mo ni oye o!
oye o oye o!
Oro aye mi ye o
iwo lomo ibi bata gbe Tami lese
edumare dakun wa ba mi bo roro itura si
mi o Fe sesese lalari rere
Ara ire ni ko Fi aye mi da o o o!!
iwo ni alaara
edumare!!!
Fi mi dara ire
Fi mi dara ire
iwo ni alaara
kabiyesi !!!
Fi mi dara ire
Fi mi da ire
iwo ni alaara
iwo ni alaara
Fi mi dara ire
Eni ara ire ba Wu
iwo ni alaara
oba oke
Fi mi dara ire ire