![Ifekofaari](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/06/8a8649973e804be991cc87ed4c90f614_464_464.jpg)
Ifekofaari Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Ifekofaari - Emeka Indo
...
...........
I just wanna let you know that i love you so much
You're the cutest, sexiest, finest, prettiest lady have ever seen
I wanna make you my woman
I wanna make my angel
Babygirl, be the queen of my heart
Jẹ n mu e rele X2
Ile baba mi, mofẹ fi e s'aya
Je n mu ẹ relé ooo
Kín mu e relé
Ile mama mi, àní mofẹ fi e s'aya
Otale nigba ẹyẹ ni n bẹ nígbó
ṣugbọn iwọ l'olori wọn
Arẹwa yi n fò bí ẹyẹ sugbon labalaba kole dàbí ẹyẹ iwọ
Onitemi
Give me the key
To the door
Of your heart huuu
I wanna live there forever
I go die on top your matter I will never never let you go
Ìfẹ rẹ n pami bi oti
Je n mu e relé yeh
Je n mu e relé
Ile baba mi mo fẹ fi e s'aya
Jẹ n mu e rele ooo
ki n mu ẹ relé
ile mama mi, àní mo fẹ fi e s'aya
Bi ma delẹ in the all night
Iwọ leni na ti mo fẹràn
Arewa wa, kajo rìnrìn àjò
Irin ajo ìfẹ Cos
I'm nothing yeh
Nothing without you
I'm nothing
I'm lost without you
I wanna make you my woman
I wanna make my angel
Babygirl, be the queen of my heart
Jẹ n mu e rele X2
Ile baba mi, Ile baba to bi lomo óò
mofẹ fi e s'aya
Orekelewa
Je n mu ẹ relé
Ìfẹ kọ faari ooo
Je n mu e relé
Ìfẹ kọ faari
Ile mama mi, ile mama mi, mofẹ fi e s'aya
Ahhh..
Jẹ n mu ẹ relé
Jẹ n mu ẹ relé yeh
Ìfẹ kọ faari e e
Mofẹ fi e s'aya ni e e
............