![Kolo 1](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/07/89dc309c2bda44a3b598e3b139b58902_464_464.jpg)
Kolo 1 Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Kolo 1 - Emeka Indo
...
Uh uh yeah
Yee e e
Oro re ni
Oro re ni
Oro re ni
Nikose
Oro re ni
Oro re ni
Oro re ni
Nikose
Mofe ma gbo ohun re
Shimi leti inu
Lati ma gbo ohun re
Kima pegan ogo re
Mogbadura si baba
Oro re ni
Oro re ni
Oro re ni
Nikose
Oloun jowo oo mashe dakee
mashe dakee lori Oro ayemi
Maje Sonu kin to Sonu
Ibimore iwo loye
irinajo ayemi iwolomo
(Chorus)
Baba ye
Baba ye
Jowo ooo, to isise mi
Baba ye
Baba ye
Jowo ooo, to isise mi.
Kirakita Eda nko ni mu ni la
ibunkun oloun ni muni la
Laini nlala ninu
ka shishe bi eru Koda nkankan
ibunkun olorun ni muni nla se
ibi ntawa nre ko jina sugbon ibi yawa nya lojin
oye lo Sonu lowo wa ntawa ko Fi Fi Oro wa le oloun lowo