![Kolo 2](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/07/89dc309c2bda44a3b598e3b139b58902_464_464.jpg)
Kolo 2 Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Kolo 2 - Emeka Indo
...
Ayafeni toluwa ba pe
Ayafeni to ran nise ree
Agbelebu Jesu, o dun otun koro
Eda jọwọ k'iye sara
.......
Ayafeni Toluwa ba pe
Ayafeni to ran nise ree....
Agbelebu Jesu, O dun otun koro
Eda jọwọ k'iye sara
Moduro le kristi Apata
ilẹ mimọ, iyan mi ni
Moduro le kristi Apata
ilẹ mimọ iyan mi ni...
Maje n jabọ X3
Ọlọrun
Maje n jabọ X2
Di mi mu ooo, Ọlọrun
.......
Awọn to fẹ lope
Awọn to pe lo Yan
Awọn to Yan lo se l'ogo
Baba ka mi Mon wọn
Kami mo awon tiyo jo'gun iye
Kami mọ awọn ti o ba e jọba
Ipe to pe mi e e, Ipe ogo ni
Baba ma je n sope nu
(Chorus)
Ayafeni t'ọlọrun ba pe
Ayafeni to ran nise ree
Agbelebu Jesu, o dun otun koro
Eda jọwọ k'iye sara
Ayafeni t'ọlọrun ba pe
Ayafeni to ran nise ree
Agbelebu Jesu, o dun otun koro
Eda jọwọ k'iye sara.......