Faanu Yanju Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Faanu Yanju - Yinka Ayefele
...
(Instrument)
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Jesu ko wa f'oro mi
Se iyanu sii...
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Jesu ko wa f'oro mi
Se iyanu sii...
(Instrument)
Niibi to sin mi de o Jesu,
Iwo nikan lo ye, ko le y'enikan...
Ibi ti o si n tun mu mi lo,
Iwo nikan lo ye, ko le y'enikan
Boju wole, gb'ebe mi
Tun mbo maa sh'ona mi ni'rere
Mo ti di'ro mon o oh
Mo ti di'ro mon o oh
Mo o di'ro mon o oh
Tun mbo maa sh'ona mi ni'rere
(Instrument)
Mu se o laaye mi o
Mu se o Atobiju
Wa mu se o Olorun Igbala
Ileri ayo Re to se
Mu se o laaye mi o
Mu se o Atobiju
Wa mu se o Olorun Igbala
Ileri ayo Re to se
(Instrument)
Olorun, s'oro Re lee kan sii
Bi'se Re ninu laye mi
T'afoju gbo, to si riran
T'aditi, to sii gb'oran
Ti aro gbo, to fo f'ayo
Olorun wa s'oro iye Re s'aye mi
Gege bi ise Re Oluwa,
Olorun wa Saanu mi o.
Mo ti di'ro mon o oh
Mo ti di'ro mon o oh
Mo o di'ro mon o oh
Baba wa f'oro mi se'yanu sii
(Instrument)
Baba, maa je ki Igbala mi koja mi lo,
da gba mi pada fun mi o,
Mu Igbala Re wo inu Ile mi,
Olorun mi Saanu mi o
Mu Igbala Re wo inu aye mi
Pa se igbe dide Re Oluwa.
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Jesu ko wa f'oro mi
Se iyanu sii... 2ce
(Instrument )
Ohun Ota gba danu lowo mi
Nipa ese mi, Wa won ri o
Da won pada fun mi o, Baba
Kan tun di lilo fun ogo Re
Ma je n jin si koto aye,
Eleda mi Saanu mi o.
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Faanu yanju Oro mi
Jesu ko wa f'oro mi
Se iyanu sii... 2ce
(Instrument )
Added by:
Adewumi Olumuyiwa Daniel