Ekundayo Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:2020
Lyrics
Ekundayo - Yinka Ayefele
...
interlude
fanu yaju oro mi X3, Jesu ko wa foro mi se iyanu si.
fanu yaju oro mi X3 Jesu ko wa foro mi se iyanu si (interlude)
ibi to sin mi de o Jesu,iwo nikan lo ye,ko Le yeenikan
ibi to sin tun mu min lo,iwo nikan lo ye ko Le yeenikan,
bo ju wole,legbe mi,tubo ma so no mi ni rere
mo ti diro mo o o X2
ooo diro mo o o,tubo ma sona mi ni rere
(interlude)
kuse o laye mi o
kuse o atobiju