Iyin Ogo Ye O Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Iyin Ogo Ye O - Yinka Ayefele
...
Beat..........
Iyin ogo ye o yin x2
modupe baba
iyin ogo ye o yin
mo mopewa baba o
iyin Ogo ye o yin
Instrument...
E fun pe no kikan
Ipe iyin rere
Ogun Jake jado
keti gbo gbo re da
odun idasile ti de
padaa elese pada
odun idasile ti de
pase elese pada