Mi O Mo J'orin Lo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2003
Lyrics
Mi O Mo J'orin Lo - Yinka Ayefele
...
Agogo pelu seke
Bo see n lo ni'waju
Ti awon ol'omele ba was tele won
Sola international drummer ma bawon bo o
Eyin oni guitar o! E ma tele won bo o
Gege bi akosile owo yin da o
C: Eje ka rowo yin o!
Ayefele ti bere ni yen ke bo sagbo