Ekundayo Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:2020
Lyrics
Ekundayo - Yinka Ayefele
...
Jesu ye titi aye, nko ni y'ese
Jesu ye titi aye, nko ni y'ese
Gege bi igi t'o duro leba odo
N'ko ni y'ese
Gb'adura funmi baba, ma je ki n se o
Gb'adura funmi baba, ma je ki n se o
Nigba ti Esu ba gbe adanwo re de,
Ma je ki n se o
Jesu ye titi aye, nko ni y'ese
Jesu ye titi aye, nko ni y'ese
Gege bi igi t'o duro leba odo
N'ko ni y'ese
Gb'adura funmi baba, ma je ki n se o
Gb'adura funmi baba, ma je ki n se o
Nigba ti Esu ba gbe adanwo re de,
Ma je ki n se o
Baba se b'iwo lo pe mi o
Pe k'emi ma bo mo de
Baba jo ma je k'aye pa kadara mi da
Baba se b'iwo lo pe mi o 'yefele
Pe k' emi ma bo mo ti de
Baba jo ma je k'aye pa kadara mi da
M'afoya ni apa Jese,
K'o s'oun eru kankan,
B'ina ti nko ko le sunmo o
Ogun Esu to do wiwo mole
M'o ro mo Agbelebu e
M'o ka Ohun gbogbo s'asan
M'a beru ire okan mi
Ayo mbe ninu Eje Jesu.
Iwo ni nma yin logo o baba
Iwo ni nma yin logo o baba
Olorun t'o gbo Adura mi ni 'gba iponju
Iwo t' o gba okan mi lowo iku aitojo
Iwo t'o gba okan mi lowo iku aitojo
O tun gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
O gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
M'o fi Ope atiyin fun o Olorun Ododo
Iwo ni nma yin logo o baba
Iwo ni nma yin logo o baba
Olorun t'o gbo Adura mi ni 'gba iponju
Iwo t' o gba okan mi lowo iku aitojo
Iwo t'o gba okan mi lowo iku aitojo
O tun gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
O gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
M'o fi Ope atiyin fun o Olorun Ododo
Iwo t'o gba okan mi lowo iku aitojo
Be e o tun gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
O se o Jesu omo Mary gb'ope gba'yin mi
Iwo ni nma yin logo o baba
Iwo ni nma yin logo o baba
Olorun t'o gbo Adura mi ni 'gba iponju
Olorun t' o gbo Adura mi ni 'gba iponju
Iwo t' o gba okan mi lowo iku aitojo
Iwo t'o gba okan mi lowo iku aitojo
O tun gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
O gbe mi soke ga ju ota mi lo nigbagbogbo
M'o fi Ope atiyin fun o Olorun Ododo
(interlude)
Duru wura nke tantan
Yi agbala Orun ka
Adun L'ohun orin won
Ti awon Angeli nko
Pelu iyin nlanla
Nwon te ori won ba
Pelu ibowo nlanla
Nwon so f'ogo f'oba orun
Ogo Ogo.. Ogo fun baba
Eleda orun oun aiye....
Alleluyia, Alleluyia
Hossana L'ohun Orin won..
Alleluyia, Alleluyia
Hossana L'ohun Orin won
Oba t'o nyi oju ojo pada
Baba wa, wa Yi aiye mi pada si re
Oba to, to nyi oju ojo pada
Yi ojo aiye mi pada si re wo 'nu Ogo tuntun si
Oba t'o nyi oju ojo pada
Baba wa, wa Yi aiye mi pada si re
Oba to, to nyi oju ojo pada
Yi ojo aiye mi pada si re wo 'nu Ogo tuntun si
B' okunkun nsu imole si ma a tan
B' iji ba nfe mo l'o si ma dake je
Oba to, tun nyi oju ojo pada
L'oju aye mi Dabo wa f'oro mi s'e 'yanu si
Oba t'o nyi oju ojo pada
Baba wa, wa Yi aiye mi pada si re
Oba to, to nyi oju ojo pada
Yi ojo aiye mi pada si re wo 'nu Ogo tuntun si
Oba t'o nyi oju ojo pada
Baba wa, wa Yi aiye mi pada si re
Oba to, to nyi oju ojo pada
Yi ojo aiye mi pada si re wo 'nu Ogo tuntun si
(interlude)
Jesu Olubaso okan mi,
Ore ti ko ni k'o ni sile
Oba to nso ekun d' ayo
Olutunu okan ni
Jehovah nissi, Oluwa
Opagun mi M'o dupe
Fun 'dasile ijo mimo
TO s' oju emi I mi
Laarin ota, laarin idamu
O K'o fi mi fun 'ji aye
Ha Oluwa mi Modupe
Modupe mo..dupe
Jesu ni ayo mi, oun sa ni ayo mi.
Iku ri mi sa, ntor' oun layo mi
Aisan ri mi sa, ntor'oun layo mi
Jesu oba ti nso ekun d'ayo
Oluwa mo dupe
Oba ti nso, ti nso ekun d'ayo
Oluwa mo dupe
Jesu Olubaso okan mi,
Ore ti ko ni k'o ni sile
Oba to nso ekun d' ayo
Olutunu okan ni
Jehovah nissi, Oluwa
Opagun mi M'o dupe
Fun 'dasile ijo mimo
TO s' oju emi I mi
Laarin ota, laarin idamu
O K'o fi mi fun 'ji aye
Ha Oluwa mi Modupe
Modupe mo..dupe
Ha Oluwa mi modupo
Modupe mo..dupe
Interlude
Lyrics unknown......
Baba mi Olorun mi,
M' o fi 'rele sunmo o
Je ki n r' ayo mu de'le
Baba mi Olorun mi.
M'o fi igbagbo beere
Ogo nla latorun wa
Igbagbo ti ko mikan
Ti ko je S'iye meji
Eyin Jesu, Eyin Jesu