
Jesu Awa Yio Sin O Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2022
Lyrics
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
N'íbi mímọ́ yìí
L'áàrin ìjọ nlá Rẹ
Àwa yíò sìn Ọ́
Títí d'ópin
Àwa yíò mú 'bùkún re'lé
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
N'íbi mímọ́ yìí
L'áàrin ìjọ nlá Rẹ
Èmi ó sìn Ọ́
Títí d'ópin
Èmi ó mú 'bùkún re'lé
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
Jesu
Àwa yíò sìn Ọ́
N'íbi mímọ́ yìí
L'áàrin ìjọ nlá Rẹ
Àwa yíò sìn Ọ́
Títí d'ópin
Àwa yíò mú 'bùkún re'lé
Àmín