
Baba Rere (Odun n lo s'opin) Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2022
Lyrics
Hmmmnnn yeah
Ah ah ah ah ah ah
Eledumare
You kept us going from January till now
And by Your mercy, through troubles we survived
And now just few more days till the end
Let's count our blessings and be grateful we're alive
Má mà jẹ k'ọta yọ wa o Baba Rere
K'aye wa ko dun, ko dara o Baba Rere
For You're The Comforter and bringer of good tidings
And like the Angels announced Your birth with joy
K'aye wa l'ẹwa, ko tun toro minimini
K'íṣẹ́ wa l'érè, ko ma d'ìṣẹ́ o Baba Rere
Ọdun nlọ s'opin o o o o
Baba maa ṣọ wa o tọmọtọmọ
Ohun ti yo pa wa lẹkun o l'ọdun tuntun
Má mà jẹ ko ṣẹlẹ si wa o Baba Rere
Ọdun nlọ s'opin o o o o o
Baba Maa ṣọ wa o tọmọtọmọ
Ohun ti yo pa wa lẹkun o l'ọdun tuntun
Má mà jẹ ko ṣẹlẹ si wa o Baba Rere
Tu wa ninu o o ye tu wa ninu
Rẹ wa l'ẹkun o o rẹ wa l'ẹkun
Jẹ ki ọdun to n bọ ko yabo fun gbogbo wa
Ẹbẹ la n bẹ Ọ o o o
Baba Rere