Olugbala Gbohun Mi
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Olugbala gbohun mi Gbohun mi, gbohun mi Mo wa sodo Re gba mi Nibi agbelebu Emi se, sugbon O ku Iwo ku, Iwo ku Fi anu Re pa mi mo Nibi agbelebu Oluwa jo gba mi Nk'y'o bi O n'inu mo Alabukun gba mi Nibi agbelebu Bi n o ba tile segbe N o bebe, n o bebe Iwo ni Ona, iye Nibi agbelebu Ore ofe Re ta gba Lofe ni, lofe ni Foju anu Re wo mi Nibi agbelebu Oluwa jo gba mi Nk'y'o bi O n'inu mo Alabukun gba mi Nibi agbelebu Feje mimo Re we mi Fi we mi, fi we mi Ri mi sinu ibu Re Nibi agbelebu Gbagbo lo le fun wa ni Dariji, dariji Mo figbagbo ro mo O Nibi agbelebu Oluwa jo gba mi Nk'y'o bi O n'inu mo Alabukun gba mi Nibi agbelebu
Similar Songs
More from Adeola Olugbesan
Listen to Adeola Olugbesan Olugbala Gbohun Mi MP3 song. Olugbala Gbohun Mi song from album Olugbala Gbohun Mi is released in 2021. The duration of song is 00:05:36. The song is sung by Adeola Olugbesan.
Related Tags: Olugbala Gbohun Mi, Olugbala Gbohun Mi song, Olugbala Gbohun Mi MP3 song, Olugbala Gbohun Mi MP3, download Olugbala Gbohun Mi song, Olugbala Gbohun Mi song, Olugbala Gbohun Mi Olugbala Gbohun Mi song, Olugbala Gbohun Mi song by Adeola Olugbesan, Olugbala Gbohun Mi song download, download Olugbala Gbohun Mi MP3 song