
Sami Iye Si Wa Lara Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2022
Lyrics
Hmmmnnn ye Elédùmarè
Ṣọ́ lílọ àti bíbọ̀ mi o o o
Ìyè
Ewu má ya ilé mi
Bí mo jókòó sílé
Àrùn yàgò lọ́nà mi
Bí mo jáde nílé
Bí mo pè Ọ́ o e, Ẹlẹ́dá mi
Lówúrọ̀, lóru, dàbò Rẹ bò mí
Sa àmì ìyè yí o (Bàbá sa àmì ìyè sí wa lára o)
Sa àmì ìyè yí o (Bàbá sa àmì ìyè sí wa lára o)
Yeh, ikú mbẹ lóde (Sa àmì ìyè sí wa lára o)
Àrùn mbẹ níta (Sa àmì ìyè sí wa lára o)
Sa àmì Ìyè yí o (Bàbá sa àmì Ìyè sí wa lára o)
Sa àmì Ìyè yí o (Bàbá sa àmì ìyè sí wa lára o)
Yeh, ikú mbẹ lóde (sa àmì sí wa lára o)
Àrùn mbẹ níta (Sa àmì Ìyè sí wa lára o)
Kí ikú rí wa kó kọjá, (Sa àmì ìyè si wa lára o)
Ki àrùn rí wa kó wọlẹ̀, sa àmì ìyè sí wa lára ooo
Ṣọ lilọ àti bibọ mi o o, iye
Orí sún mi báre
Tọ́ mi sọ́nà wọnú ire
Yee eh oh
Àkòyà ìṣẹ́ o eee
Kọ́nà mi là sí rere
Bí mo ké pè Ọ́ o e
Ẹlẹ́dá mi
Má mà ṣàì gbà mí o e
Lọ́wọ́ aṣebi
Sa ami iye yi o (Baba sa ami iye si wa lara o)
Sa ami iye yi o (Baba sa ami iye si wa lara o)
Yeh, iku mbẹ lode (Sa ami iye si wa lara o)
Arun mbẹ ni'ta (Sa ami iye si wa lara o)
Sa ami Iye yi o (Baba sa ami Iye si wa lara o)
Sa ami iye yi o (Baba sa ami iye si wa lara o)
Eh, iku mbẹ lode (Sa ami si wa lara o)
Arun mbẹ nita (Sa ami iye si wa lara o)
Ki iku ri wa ko kọja (Sa ami iye si wa lara o)
Ki arun ri wa ko wọlẹ̀ (Sa àmì ìyè si wa lara o)
Ami igbala yi la fẹ o
Àrìnàkore Àkòyà ibi
Ki ọna mi la si rere
Ki ori mi ma gbabọde fún mi o ye e e e
Me ra rọran laye mi o ye e e e e e e e
Ta pa ra ra pa ra pa pa
Ta ra pa ra ra pa pa ra raaaaa
Ahhh iye re o,
Iye re o o o ìyè re o
Iye iye iye eee
Iye iye iye eeeee, eh eh eh eh (Ìyè sí wa lára)
Oh oh oh mmm hmmm eh hen (Iye si wa lara)
Oh oh oh iye re o eh hen
Oriburuku yago lọna mi oo eh
Igokegodo mi ko ja sire ye ooo
Tẹbi tara mi o ni yànkú o ìyè ni tawa
Kíṣẹ́ mi má dìṣẹ́ o e iye ni temi
Bi mo duro ki n rire
Bi mo tun bẹrẹ ki n rire
Ire ọla ire aiku baalẹ ọrọ̀
Ẹni ba pe n ma yè
Ko dẹni agbegbin
Itakun to ni keerin ma wọdo ye o o
Tohun teerin ni yo jọ lọ ah ah
O da
Iye re iye re iye re