
Odun Nlo Sopin Collaboration ft. Daystar Christian Centre's Healing Streams of God Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:2015
Lyrics
Odun Nlo Sopin Collaboration ft. Daystar Christian Centre's Healing Streams of God - C.A.C Good Women Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin
...
Keresimesi odun de oo>2
Keresimesi Odun de Odun de odun de
Odun ti de...de Odun oloyin
Odun oloyinnnnnnnn>2
Odunn ti deeeeee
Odun yi atura koni le koko momiii
Keresimesi odun de odun,odun odun odun yi atura ko ni lekoko momiii
Oun ti mo dawoleeee
Aayo riiiiii
Oun ti mo beeere
Loluwa yo sheeeee eh eh
Odun yi atura
Atura
Odun yi atura tura atura
Odun yi atura ko ni le koko mo miiii
Beat>>>
Odun nlo sopin ooo baba re re
Baba ma showa ooo
Tomotomo
Oun ti o pawa lekun o lodun titun
Maje kosele si waaaa o
Baba rere>2
Ma je kin kowolori sokun
Ma jein daso ofo boraa
Ogun roju je roju mu
Ma ma je o je ti temi
Alafia pi pe ni mo Fe fi tamilore
Jein ri na, jein ri lo
Baba wa semilogo
Ma jein tawo na
Majein taraka lodun tuntun
Dabo olorun ni dabo>2
Mama je kan fi iretemi sapinle (Lodun titun)
Mama je koroml jasofo lodo ree
Dabo olorun mi dabo
Aaaaaaaaa
Baba eleruniyin wasure fun wa
Ani karona gbegba lodun titun
Aaaaaaaa
Baba eleruniyin wasure fun wa
Ani karona Gbegba lodun toun wole
Tun won ninu ,Oluwa tu won ninu
Agan ti ko romo gbepon tu won ni nu oluwa(dakun ye oooooo>2
Re won lekun oluwa rewonlekun awon to Dabi Hannah re won lekun oluwa(dakun ye o>2 dakun ye o oluwa)
Ododun lanrorogbo
Ododun lanrawusa
Kodun kosanwa sowo
Kodun kosanwa somo
Karibatise
Kodun yaaa bo
Karona gbegba
Ani kama toro je
Ani Kama Toromuu
Kama wo akisa kehin aso baba gbotiwa
Kama se rogun ejo
Bawa Segun Aisan
Ogun asedanu ogun akowaba bawa se
Abo re to daju lawa nfe lodun toun wole
Oun rere to ye waaa
Baba fise wa logooo
Oun ti yo pawa lekun oooo ninu odun
Maje kosele si Waa o Baba rere
In Jesus Mighty Name
It is well with us